Otito Re wuwo

 


1. Otito Re wuwo, Bab’ Olorun mi,
Ko si ayidayida lodo Re;
‘Wo ko yi pad’ anu Re ko kuna ri,
Bi O ti wa, beeni y’o wa titi.


Egbe
Otito Re wuwo, otito Re wuwo,
Laraaro anu tuntun ni mo n’ri,
Gbogb’ ohun mo fe lowo Re ti pese,
Otito Re tobi pupo si mi


2. Igba oru, oye, oj’ ati ‘kore,
Orun, osupa, ‘rawo lona won
Dapo m’eda gbogbo ni’jeri si re
Otito nla, anu at’ ife Re.


3.’Dariji ese, alafia to daju,
‘Walaye Re to n ‘tunu to ndari;
Agbar’oni, iret’ola t‘o daju,
Ibukun ainiye si je t’emi.

or


Otito Re tobi, Bab’ Olorun mi,
Ko si ayidayida lodo Re;
‘Wo ko yi pad’ anu Re ko kuna ri,
Bi O ti wa, beeni O wa titi.


Egbe
Otito Re tobi, otito Re tobi.
Laraaro anu tuntun ni mo n ri,
Gbogb’ ohun mo fe lowo Re ti pese,
Otito Re tobi pupo si mi


Igba oru, oye, oj’ ati ‘kore,
Orun, osupa, ‘rawo lona won
Dapo m’eda gbogbo ni ijeri si
Otito nla, anu at’ ife Re.


‘Dariji ese, alafia to daju,
‘Walaye Re to n ‘tunu to n dari;
Agbara fun oni, ireti f’ ola,
Ibukun ainiye si je temi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *