Baba wa Ti n be Lorun

 


Baba wa ti’n be l’orun
K’a bowo f’oruko re Ki ijoba re de
K’a she ‘fe re ‘laiye
B’ won ti’n se l’orun o!
Fun wa l’ounje ti ojo oni
Dari ese ji wa B’awa n’se dariji
Ma fa wa si nu idanwo Gba wa nu bilisi
T’ori ‘joba ni ti ire
Ati agbara, Ogo ni t’ ire
Titi l’aiye Amin.

Leave a Reply

Your email address will not be published.